Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 43 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿مَا تَسۡبِقُ مِنۡ أُمَّةٍ أَجَلَهَا وَمَا يَسۡتَـٔۡخِرُونَ ﴾
[المؤمنُون: 43]
﴿ما تسبق من أمة أجلها وما يستأخرون﴾ [المؤمنُون: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìjọ kan kò níí lọ ṣíwájú àkókò (ìparun) rẹ̀, wọn kò sì níí sún (ìparun wọn) síwájú |