Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 14 - الفُرقَان - Page - Juz 18
﴿لَّا تَدۡعُواْ ٱلۡيَوۡمَ ثُبُورٗا وَٰحِدٗا وَٱدۡعُواْ ثُبُورٗا كَثِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 14]
﴿لا تدعوا اليوم ثبورا واحدا وادعوا ثبورا كثيرا﴾ [الفُرقَان: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A ó sọ pé): “Ẹ má ṣe kígbe ìparun ẹyọ kan, ẹ kígbe ìparun lọ́pọ̀lọ́pọ̀.” |