Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 23 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَقَدِمۡنَآ إِلَىٰ مَا عَمِلُواْ مِنۡ عَمَلٖ فَجَعَلۡنَٰهُ هَبَآءٗ مَّنثُورًا ﴾
[الفُرقَان: 23]
﴿وقدمنا إلى ما عملوا من عمل فجعلناه هباء منثورا﴾ [الفُرقَان: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé A máa wá ṣíbi ohun tí wọ́n ṣe níṣẹ́, A sì máa sọ ọ́ di eruku àfẹ́dànù |