Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 30 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَقَالَ ٱلرَّسُولُ يَٰرَبِّ إِنَّ قَوۡمِي ٱتَّخَذُواْ هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانَ مَهۡجُورٗا ﴾
[الفُرقَان: 30]
﴿وقال الرسول يارب إن قومي اتخذوا هذا القرآن مهجورا﴾ [الفُرقَان: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òjíṣẹ́ náà sọ pé: “Olúwa mi dájúdájú àwọn ènìyàn mi tí pa al-Ƙur’ān yìí tì.” |