Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 64 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَٱلَّذِينَ يَبِيتُونَ لِرَبِّهِمۡ سُجَّدٗا وَقِيَٰمٗا ﴾
[الفُرقَان: 64]
﴿والذين يبيتون لربهم سجدا وقياما﴾ [الفُرقَان: 64]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn ni) àwọn t’ó ń lo òru wọn ní ìforíkanlẹ̀ àti ìdúró-kírun fún Olúwa wọn |