Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 146 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿أَتُتۡرَكُونَ فِي مَا هَٰهُنَآ ءَامِنِينَ ﴾
[الشعراء: 146]
﴿أتتركون في ما هاهنا آمنين﴾ [الشعراء: 146]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé kí wọ́n fi yín sílẹ̀ síbi n̄ǹkan tí ó wà (nílé ayé) níbí yìí (nínú ìgbádùn ayé, kí ẹ jẹ́) olùfọkànbalẹ̀ |