Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 201 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿لَا يُؤۡمِنُونَ بِهِۦ حَتَّىٰ يَرَوُاْ ٱلۡعَذَابَ ٱلۡأَلِيمَ ﴾
[الشعراء: 201]
﴿لا يؤمنون به حتى يروا العذاب الأليم﴾ [الشعراء: 201]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí gbà á gbọ́ ní òdodo títí wọn yóò fi rí ìyà ẹlẹ́ta-eléro |