Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 22 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿وَلَمَّا تَوَجَّهَ تِلۡقَآءَ مَدۡيَنَ قَالَ عَسَىٰ رَبِّيٓ أَن يَهۡدِيَنِي سَوَآءَ ٱلسَّبِيلِ ﴾
[القَصَص: 22]
﴿ولما توجه تلقاء مدين قال عسى ربي أن يهديني سواء السبيل﴾ [القَصَص: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí ó sì dojú kọ ọ̀kánkán ìlú Mọdyan, ó sọ pé: “Ó súnmọ́ kí Olúwa mi fọ̀nà tààrà (sí ìlú Mọdyan) mọ̀ mí.” |