Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 43 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿يَٰمَرۡيَمُ ٱقۡنُتِي لِرَبِّكِ وَٱسۡجُدِي وَٱرۡكَعِي مَعَ ٱلرَّٰكِعِينَ ﴾
[آل عِمران: 43]
﴿يامريم اقنتي لربك واسجدي واركعي مع الراكعين﴾ [آل عِمران: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mọryam, tẹ̀lé àṣẹ Olúwa rẹ. Forí kanlẹ̀ fún Un. Kí o sì dáwọ́ tẹ orúnkún pẹ̀lú àwọn olùdáwọ́tẹ-orúnkún (lórí ìrun) |