Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 49 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿وَإِن كَانُواْ مِن قَبۡلِ أَن يُنَزَّلَ عَلَيۡهِم مِّن قَبۡلِهِۦ لَمُبۡلِسِينَ ﴾
[الرُّوم: 49]
﴿وإن كانوا من قبل أن ينـزل عليهم من قبله لمبلسين﴾ [الرُّوم: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ṣíwájú kí Ó tó sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún wọn, wọ́n ti sọ̀rètí nù ṣíwájú rẹ̀ |