Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 39 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَٱلۡقَمَرَ قَدَّرۡنَٰهُ مَنَازِلَ حَتَّىٰ عَادَ كَٱلۡعُرۡجُونِ ٱلۡقَدِيمِ ﴾
[يسٓ: 39]
﴿والقمر قدرناه منازل حتى عاد كالعرجون القديم﴾ [يسٓ: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òṣùpá náà, A ti ṣe òdíwọ̀n àwọn ibùsọ̀ fún un (tí ó ti ma máa tóbi sí i) títí ó máa fi padà dà bíi ọ̀gọ́mọ̀ ọ̀pẹ t’ó ti pẹ́ |