Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 50 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿فَلَا يَسۡتَطِيعُونَ تَوۡصِيَةٗ وَلَآ إِلَىٰٓ أَهۡلِهِمۡ يَرۡجِعُونَ ﴾
[يسٓ: 50]
﴿فلا يستطيعون توصية ولا إلى أهلهم يرجعون﴾ [يسٓ: 50]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà náà, wọn kò níí lè sọ àsọọ́lẹ̀ kan. Wọn kò sì níí lè padà sí ọ̀dọ̀ ará ilé wọn |