Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 49 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿مَا يَنظُرُونَ إِلَّا صَيۡحَةٗ وَٰحِدَةٗ تَأۡخُذُهُمۡ وَهُمۡ يَخِصِّمُونَ ﴾
[يسٓ: 49]
﴿ما ينظرون إلا صيحة واحدة تأخذهم وهم يخصمون﴾ [يسٓ: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò retí kiní kan bí kò ṣe igbe ẹyọ kan ṣoṣo tí ó máa gbá wọn mú nígbà tí wọ́n bá ń ṣe àríyànjiyàn lọ́wọ́ |