Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 105 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿قَدۡ صَدَّقۡتَ ٱلرُّءۡيَآۚ إِنَّا كَذَٰلِكَ نَجۡزِي ٱلۡمُحۡسِنِينَ ﴾
[الصَّافَات: 105]
﴿قد صدقت الرؤيا إنا كذلك نجزي المحسنين﴾ [الصَّافَات: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni o kúkú ti mú àlá náà ṣẹ. Dájúdájú báyẹn ni Àwa ṣe ń san àwọn olùṣe-rere ní ẹ̀san (rere) |