Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 48 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَعِندَهُمۡ قَٰصِرَٰتُ ٱلطَّرۡفِ عِينٞ ﴾
[الصَّافَات: 48]
﴿وعندهم قاصرات الطرف عين﴾ [الصَّافَات: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn obìnrin tí kì í wo ẹlòmíìràn, àwọn ẹlẹ́yinjú ẹgẹ́ yó sì wà lọ́dọ̀ wọn |