Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 99 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَقَالَ إِنِّي ذَاهِبٌ إِلَىٰ رَبِّي سَيَهۡدِينِ ﴾
[الصَّافَات: 99]
﴿وقال إني ذاهب إلى ربي سيهدين﴾ [الصَّافَات: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Dájúdájú mo máa lọ sí (ìlú tí) Olúwa mi (pa mí láṣẹ láti lọ). Ó sì máa tọ́ mi sọ́nà (láti dé ibẹ̀) |