Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 33 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿وَٱلَّذِي جَآءَ بِٱلصِّدۡقِ وَصَدَّقَ بِهِۦٓ أُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡمُتَّقُونَ ﴾
[الزُّمَر: 33]
﴿والذي جاء بالصدق وصدق به أولئك هم المتقون﴾ [الزُّمَر: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí ó sì mú òdodo wá (ìyẹn, Ànábì Muhammad s.a.w.) àti (àwọn) ẹni t’ó gbà á gbọ́ ní òdodo; àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni olùbẹ̀rù (Allāhu) |