Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zumar ayat 34 - الزُّمَر - Page - Juz 24
﴿لَهُم مَّا يَشَآءُونَ عِندَ رَبِّهِمۡۚ ذَٰلِكَ جَزَآءُ ٱلۡمُحۡسِنِينَ ﴾
[الزُّمَر: 34]
﴿لهم ما يشاءون عند ربهم ذلك جزاء المحسنين﴾ [الزُّمَر: 34]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ohunkóhun tí wọ́n bá ń fẹ́ wà fún wọn ní ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. Ìyẹn sì ni ẹ̀san àwọn ẹni rere |