Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 66 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿هَلۡ يَنظُرُونَ إِلَّا ٱلسَّاعَةَ أَن تَأۡتِيَهُم بَغۡتَةٗ وَهُمۡ لَا يَشۡعُرُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 66]
﴿هل ينظرون إلا الساعة أن تأتيهم بغتة وهم لا يشعرون﴾ [الزُّخرُف: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé wọ́n ń retí kiní kan bí kò ṣe Àkókò náà; tí ó máa dé bá wọn ní òjijì; wọn kò sì níí fura |