Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 67 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿ٱلۡأَخِلَّآءُ يَوۡمَئِذِۭ بَعۡضُهُمۡ لِبَعۡضٍ عَدُوٌّ إِلَّا ٱلۡمُتَّقِينَ ﴾
[الزُّخرُف: 67]
﴿الأخلاء يومئذ بعضهم لبعض عدو إلا المتقين﴾ [الزُّخرُف: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ọ̀rẹ́ àyò ní ọjọ́ yẹn, apá kan wọn yóò jẹ́ ọ̀tá fún apá kan àyàfi àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) |