Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 75 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿لَا يُفَتَّرُ عَنۡهُمۡ وَهُمۡ فِيهِ مُبۡلِسُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 75]
﴿لا يفتر عنهم وهم فيه مبلسون﴾ [الزُّخرُف: 75]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ò níí gbé e fúyẹ́ fún wọn. Wọn yó sì sọ̀rètí nù nínú Iná |