Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 18 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿أَنۡ أَدُّوٓاْ إِلَيَّ عِبَادَ ٱللَّهِۖ إِنِّي لَكُمۡ رَسُولٌ أَمِينٞ ﴾
[الدُّخان: 18]
﴿أن أدوا إلي عباد الله إني لكم رسول أمين﴾ [الدُّخان: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó sọ pé): “Ẹ kó àwọn ẹrúsìn Allāhu lé mi lọ́wọ́. Dájúdájú èmi ni Òjíṣẹ́ olùfọkàntán fun yín |