Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 17 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿۞ وَلَقَدۡ فَتَنَّا قَبۡلَهُمۡ قَوۡمَ فِرۡعَوۡنَ وَجَآءَهُمۡ رَسُولٞ كَرِيمٌ ﴾
[الدُّخان: 17]
﴿ولقد فتنا قبلهم قوم فرعون وجاءهم رسول كريم﴾ [الدُّخان: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A dán àwọn ènìyàn Fir‘aon wò ṣíwájú wọn. Òjíṣẹ́ alápọ̀n-ọ́nlé sì dé wá bá wọn |