Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 19 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿وَأَن لَّا تَعۡلُواْ عَلَى ٱللَّهِۖ إِنِّيٓ ءَاتِيكُم بِسُلۡطَٰنٖ مُّبِينٖ ﴾
[الدُّخان: 19]
﴿وأن لا تعلوا على الله إني آتيكم بسلطان مبين﴾ [الدُّخان: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ má ṣe ṣègbéraga sí Allāhu. Dájúdájú èmi ti mú ẹ̀rí pọ́nńbélé wá ba yín |