Quran with Yoruba translation - Surah Al-hujurat ayat 4 - الحُجُرَات - Page - Juz 26
﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلۡحُجُرَٰتِ أَكۡثَرُهُمۡ لَا يَعۡقِلُونَ ﴾
[الحُجُرَات: 4]
﴿إن الذين ينادونك من وراء الحجرات أكثرهم لا يعقلون﴾ [الحُجُرَات: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn t’ó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè |