Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 30 - قٓ - Page - Juz 26
﴿يَوۡمَ نَقُولُ لِجَهَنَّمَ هَلِ ٱمۡتَلَأۡتِ وَتَقُولُ هَلۡ مِن مَّزِيدٖ ﴾
[قٓ: 30]
﴿يوم نقول لجهنم هل امتلأت وتقول هل من مزيد﴾ [قٓ: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) ọjọ́ tí A óò sọ fún iná Jahnamọ pé: Ṣèbí o ti kún?" Ó sì máa sọ pé: "Ṣèbí àfikún tún wà |