Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 29 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿فَذَكِّرۡ فَمَآ أَنتَ بِنِعۡمَتِ رَبِّكَ بِكَاهِنٖ وَلَا مَجۡنُونٍ ﴾
[الطُّور: 29]
﴿فذكر فما أنت بنعمة ربك بكاهن ولا مجنون﴾ [الطُّور: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ṣèrántí. Ìwọ kì í ṣe adábigba tàbí wèrè lórí ìdẹ̀ra Olúwa rẹ |