Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 52 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿وَقَوۡمَ نُوحٖ مِّن قَبۡلُۖ إِنَّهُمۡ كَانُواْ هُمۡ أَظۡلَمَ وَأَطۡغَىٰ ﴾
[النَّجم: 52]
﴿وقوم نوح من قبل إنهم كانوا هم أظلم وأطغى﴾ [النَّجم: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àti ìjọ Nūh t’ó ṣíwájú (wọn), dájúdájú wọ́n jẹ́ alábòsí jùlọ, wọ́n sì tayọ ẹnu-àlà jùlọ |