Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 39 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿فَيَوۡمَئِذٖ لَّا يُسۡـَٔلُ عَن ذَنۢبِهِۦٓ إِنسٞ وَلَا جَآنّٞ ﴾
[الرَّحمٰن: 39]
﴿فيومئذ لا يسأل عن ذنبه إنس ولا جان﴾ [الرَّحمٰن: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ní ọjọ́ yẹn Wọn ò níí bi ènìyàn àti àlùjànnú kan léèrè nípa ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀; (ó ti wà ní àkọsílẹ̀ ní ọ̀dọ̀ Wa) |