Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 13 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿۞ وَلَهُۥ مَا سَكَنَ فِي ٱلَّيۡلِ وَٱلنَّهَارِۚ وَهُوَ ٱلسَّمِيعُ ٱلۡعَلِيمُ ﴾
[الأنعَام: 13]
﴿وله ما سكن في الليل والنهار وهو السميع العليم﴾ [الأنعَام: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni TiRẹ̀ ni ohunkóhun t’ó ń bẹ nínú òru àti ọ̀sán. Òun sì ni Olùgbọ́, Onímọ̀ |