Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 1 - المُلك - Page - Juz 29
﴿تَبَٰرَكَ ٱلَّذِي بِيَدِهِ ٱلۡمُلۡكُ وَهُوَ عَلَىٰ كُلِّ شَيۡءٖ قَدِيرٌ ﴾
[المُلك: 1]
﴿تبارك الذي بيده الملك وهو على كل شيء قدير﴾ [المُلك: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìbùkún ni fún Ẹni tí ìjọba wà ní Ọwọ́ Rẹ̀. Òun sì ni Alágbára lórí gbogbo n̄ǹkan |