Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mulk ayat 27 - المُلك - Page - Juz 29
﴿فَلَمَّا رَأَوۡهُ زُلۡفَةٗ سِيٓـَٔتۡ وُجُوهُ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ وَقِيلَ هَٰذَا ٱلَّذِي كُنتُم بِهِۦ تَدَّعُونَ ﴾
[المُلك: 27]
﴿فلما رأوه زلفة سيئت وجوه الذين كفروا وقيل هذا الذي كنتم به﴾ [المُلك: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá rí i t’ó súnmọ́, ojú àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ yóò korò wá fún ìbànújẹ́. A ó sì sọ fún wọn pé: "Èyí ni ohun tí ẹ̀ ń pè |