Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qalam ayat 19 - القَلَم - Page - Juz 29
﴿فَطَافَ عَلَيۡهَا طَآئِفٞ مِّن رَّبِّكَ وَهُمۡ نَآئِمُونَ ﴾
[القَلَم: 19]
﴿فطاف عليها طائف من ربك وهم نائمون﴾ [القَلَم: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àdánwò t’ó ń yí n̄ǹkan po láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ sì yí ọgbà náà po, nígbà tí wọ́n sùn lọ |