Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 14 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿وَحُمِلَتِ ٱلۡأَرۡضُ وَٱلۡجِبَالُ فَدُكَّتَا دَكَّةٗ وَٰحِدَةٗ ﴾
[الحَاقة: 14]
﴿وحملت الأرض والجبال فدكتا دكة واحدة﴾ [الحَاقة: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni tí wọ́n gbé ilẹ̀ àti àpáta sókè, tí wọ́n sì rún méjèèjì wómúwómú ní rírún ẹ̀ẹ̀ kan |