Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 55 - الأعرَاف - Page - Juz 8
﴿ٱدۡعُواْ رَبَّكُمۡ تَضَرُّعٗا وَخُفۡيَةًۚ إِنَّهُۥ لَا يُحِبُّ ٱلۡمُعۡتَدِينَ ﴾
[الأعرَاف: 55]
﴿ادعوا ربكم تضرعا وخفية إنه لا يحب المعتدين﴾ [الأعرَاف: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ pe Olúwa yín pẹ̀lú ìrawọ́rasẹ̀ àti ohùn jẹ́ẹ́jẹ́. Dájúdájú (Allāhu) kò fẹ́ràn àwọn alákọyọ |