Quran with Yoruba translation - Surah Nuh ayat 18 - نُوح - Page - Juz 29
﴿ثُمَّ يُعِيدُكُمۡ فِيهَا وَيُخۡرِجُكُمۡ إِخۡرَاجٗا ﴾
[نُوح: 18]
﴿ثم يعيدكم فيها ويخرجكم إخراجا﴾ [نُوح: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, Ó máa da yín padà sínú rẹ̀. Ó sì máa mu yín jáde tààrà |