Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 16 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿فَعَصَىٰ فِرۡعَوۡنُ ٱلرَّسُولَ فَأَخَذۡنَٰهُ أَخۡذٗا وَبِيلٗا ﴾
[المُزمل: 16]
﴿فعصى فرعون الرسول فأخذناه أخذا وبيلا﴾ [المُزمل: 16]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n Fir‘aon yapa Òjíṣẹ́ náà. A sì gbá a mú ní ìgbámú líle |