Quran with Yoruba translation - Surah Al-Muzzammil ayat 17 - المُزمل - Page - Juz 29
﴿فَكَيۡفَ تَتَّقُونَ إِن كَفَرۡتُمۡ يَوۡمٗا يَجۡعَلُ ٱلۡوِلۡدَٰنَ شِيبًا ﴾
[المُزمل: 17]
﴿فكيف تتقون إن كفرتم يوما يجعل الولدان شيبا﴾ [المُزمل: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ẹ̀yin bá ṣàì gbàgbọ́, báwo ni ẹ̀yin yóò ṣe bẹ̀rù ọjọ́ kan t’ó máa mú àwọn ọmọdé hewú |