Quran with Yoruba translation - Surah Al-Insan ayat 13 - الإنسَان - Page - Juz 29
﴿مُّتَّكِـِٔينَ فِيهَا عَلَى ٱلۡأَرَآئِكِۖ لَا يَرَوۡنَ فِيهَا شَمۡسٗا وَلَا زَمۡهَرِيرٗا ﴾
[الإنسَان: 13]
﴿متكئين فيها على الأرائك لا يرون فيها شمسا ولا زمهريرا﴾ [الإنسَان: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò máa rọ̀gbọ̀ kú sórí àwọn ibùsùn wọn. Wọn kò sì níí rí òòrùn tàbí òtútù |