Quran with Yoruba translation - Surah ‘Abasa ayat 37 - عَبَسَ - Page - Juz 30
﴿لِكُلِّ ٱمۡرِيٕٖ مِّنۡهُمۡ يَوۡمَئِذٖ شَأۡنٞ يُغۡنِيهِ ﴾
[عَبَسَ: 37]
﴿لكل امرئ منهم يومئذ شأن يغنيه﴾ [عَبَسَ: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn ní ọjọ́ yẹn l’ó ti ní ọ̀ràn t’ó máa tó o ó rán |