Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 53 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالُواْ لَا تَوۡجَلۡ إِنَّا نُبَشِّرُكَ بِغُلَٰمٍ عَلِيمٖ ﴾
[الحِجر: 53]
﴿قالوا لا توجل إنا نبشرك بغلام عليم﴾ [الحِجر: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: "Má ṣe bẹ̀rù. Dájúdájú àwa yóò fún ọ ní ìró ìdùnnú (nípa bíbí) ọmọkùnrin onímímọ̀ kan |