Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 54 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالَ أَبَشَّرۡتُمُونِي عَلَىٰٓ أَن مَّسَّنِيَ ٱلۡكِبَرُ فَبِمَ تُبَشِّرُونَ ﴾
[الحِجر: 54]
﴿قال أبشرتموني على أن مسني الكبر فبم تبشرون﴾ [الحِجر: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Ṣé ẹ̀ ń fún mi ní ìró ìdùnnú (nípa bíbí ọmọ) nígbà tí ogbó ti dé sí mi? Ìró ìdùnnú wo ni ẹ̀ ń fún mi ná |