Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 68 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿قَالَ إِنَّ هَٰٓؤُلَآءِ ضَيۡفِي فَلَا تَفۡضَحُونِ ﴾
[الحِجر: 68]
﴿قال إن هؤلاء ضيفي فلا تفضحون﴾ [الحِجر: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Lūt) sọ pé: “Dájúdájú àwọn wọ̀nyí ni àlejò mi. Nítorí náà, ẹ má ṣe dójú tì mí |