Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 100 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿إِنَّمَا سُلۡطَٰنُهُۥ عَلَى ٱلَّذِينَ يَتَوَلَّوۡنَهُۥ وَٱلَّذِينَ هُم بِهِۦ مُشۡرِكُونَ ﴾
[النَّحل: 100]
﴿إنما سلطانه على الذين يتولونه والذين هم به مشركون﴾ [النَّحل: 100]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni t’ó lágbára lórí rẹ̀ ni àwọn t’ó ń mú un ní ọ̀rẹ́ àti àwọn t’ó sọ ọ́ di akẹgbẹ́ Allāhu |