Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 99 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿إِنَّهُۥ لَيۡسَ لَهُۥ سُلۡطَٰنٌ عَلَى ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَلَىٰ رَبِّهِمۡ يَتَوَكَّلُونَ ﴾
[النَّحل: 99]
﴿إنه ليس له سلطان على الذين آمنوا وعلى ربهم يتوكلون﴾ [النَّحل: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú kò sí agbára kan fún un lórí àwọn t’ó gbàgbọ́, tí wọ́n sì ń gbáralé Olúwa wọn |