Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 74 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿فَلَا تَضۡرِبُواْ لِلَّهِ ٱلۡأَمۡثَالَۚ إِنَّ ٱللَّهَ يَعۡلَمُ وَأَنتُمۡ لَا تَعۡلَمُونَ ﴾
[النَّحل: 74]
﴿فلا تضربوا لله الأمثال إن الله يعلم وأنتم لا تعلمون﴾ [النَّحل: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ má ṣe fi àwọn àkàwé náà lélẹ̀ nípa Allāhu. Dájúdájú Allāhu nímọ̀; ẹ̀yin kò sì nímọ̀ |