Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 63 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿تِلۡكَ ٱلۡجَنَّةُ ٱلَّتِي نُورِثُ مِنۡ عِبَادِنَا مَن كَانَ تَقِيّٗا ﴾
[مَريَم: 63]
﴿تلك الجنة التي نورث من عبادنا من كان تقيا﴾ [مَريَم: 63]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni Ọgbà Ìdẹ̀ra tí A óò jogún rẹ̀ fún ẹni tí ó jẹ́ olùbẹ̀rù (Mi) nínú àwọn ẹrúsìn Wa |