Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 44 - طه - Page - Juz 16
﴿فَقُولَا لَهُۥ قَوۡلٗا لَّيِّنٗا لَّعَلَّهُۥ يَتَذَكَّرُ أَوۡ يَخۡشَىٰ ﴾
[طه: 44]
﴿فقولا له قولا لينا لعله يتذكر أو يخشى﴾ [طه: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ sọ ọ̀rọ̀ ẹ̀lẹ̀ fún un. Ó ṣeé ṣe kí ó lo ìṣítí tàbí kí ó páyà (Mi) |