Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 51 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَلَوۡ شِئۡنَا لَبَعَثۡنَا فِي كُلِّ قَرۡيَةٖ نَّذِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 51]
﴿ولو شئنا لبعثنا في كل قرية نذيرا﴾ [الفُرقَان: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá jẹ́ pé A bá fẹ́ ni, A ìbá gbé olùkìlọ̀ kan dìde nínú ìlú kọ̀ọ̀kan |