Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 136 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالُواْ سَوَآءٌ عَلَيۡنَآ أَوَعَظۡتَ أَمۡ لَمۡ تَكُن مِّنَ ٱلۡوَٰعِظِينَ ﴾
[الشعراء: 136]
﴿قالوا سواء علينا أوعظت أم لم تكن من الواعظين﴾ [الشعراء: 136]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Bákan náà ni fún wa; yálà o kìlọ̀ fún wa tàbí o ò sí nínú àwọn olùkìlọ̀ |